Posts

Showing posts from 2020

ÀYÁJỌ́ ỌJỌ́ ÀWỌN Ọ̀DỌ́ NÍ ÀGBÁYÉ: ÌLỌ́WỌ́SÍ Ọ̀DỌ́ FÚN ÌGBÉSẸ̀ ÀGBÁYÉ.

"ÀYÁJỌ́ ỌJỌ́ ÀWỌN Ọ̀DỌ́ NÍ ÀGBÁYÉ: ÌLỌ́WỌ́SÍ Ọ̀DỌ́ FÚN ÌGBÉSẸ̀ ÀGBÁYÉ. ~ ADÉKÚNLÉ JÓNÍSẸ. (Kunlejonise@gmail.com)." Ọjọ́ Kejìlá, Oṣù Kẹjọ Ọdọdún Ni Àjọ Àpapọ Orílé-èdè Yáà Sọ́tọ̀ Láti ṣe Ayẹyẹ Ọjọ́ Àwọn Ọ̀dọ́ Ní Àgbáyé. Àkòrí fún Àyájọ́ àwọn ọ̀dọ́ Àgbáyé ti Ọdún yìí ni "Ìlọ́wọ́sí Àwọn Ọ̀dọ́ Fún Ìgbésè Àgbáyé". Àkòrí Ọdún yìí fi àyè sílẹ̀ fún àwọn ibéèrè àti àkòrí bíi : Kíni àwọn ìyọrísí tí o ṣeéṣe tàbí àwọn àbájádèe Nígbàtí a fún àwọn Ọ̀dọ́ ní ààyè láti ṣe alábàpíín? Ìdojúko àwọ̀n Ọ̀dọ́ àti ọ̀nà àbáyọ, Kíni ẹ̀tọ́ tí àwọn Olórí Ìjọba ń ṣe láti ran àwọn Ọ̀dọ́ lọ́wọ́?" Àwon ibéèrè àti àkòrí wọ̀ǹyíì ni ó ń bẹ̀bẹ fún ìdáhùn. Tani Ọ̀dọ́? Àjọ Àpapọ̀ Orílè-èdè, fún ẹ̀ka Àwọn Ìdí, Ṣàlàyé 'Ọ̀dọ́', bíi àwọn ènìyàn láàrín ọjọ́-orí ọdún mẹ́rìndílógún sí ọdún mẹ́rinlélógún, láìsí ìkórira sí mìíràn àwọn àsọyé nípasẹ̀ àwọn Ìpínlẹ̀ ọmọ ẹgbé. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ìwádìí fi hàn pé ìpín ogójì nínú Ọgọ́rùn-ń lọ́nà Ẹgbẹ̀rún Ògún Ọ̀dọ́...